Gospel Songs

Tope Alabi ft TY Bello – Emi Mimo (Holy Spirit)

Emi Mimo by Tope Alabi ft TY Bello Mp3

A powerful Joint praise titled Logan “Emi Mimo” by Tope Alabi Ft. TY Bello

Nigerian gospel ministers, Tope Alabi and TY Bello joins voices in to birth this amazing song titled “Emi Mimo (Holy Spirit)”, the eleventh song of her Album “The Spirit of Light” which contains 17 powerful Tracks.

Listen and download the spontaneous worship from TY Bello ft Tope Alabi “Emi Mimo (Holy Spirit)

Download Emi Mimo Mp3 by Tope Alabi ft TY Bello

Listen, Download & Enjoy Below

DOWNLOAD MP3

My Money

Emi Mimo Lyrics by Tope Alabi ft TY Bello

Emi mimo, Ekaabo
Ah emi mimo, Eku ikale
Emi alaayo, Emi orun ooo
Adaba mimo, Eku ikale
Agbara to ju’aiye ati orun lo, Ekaabo
{Ekaabo, Eku ikale }x3

Odeee lati wa so okun di ogo
Odeee lati wa so ekun di erin
Odeee lati wa so ibanuje dayo
Eku ikale o, Ekaabo
Eku ikale o, Ekaabo oo
Baba eku ikale, Ekaabo

  BABA Ese - Kennywhite4rew Ft BBO (Mp3 Download, Lyrics)

Emi mimo ti n so agbara di otun
Ogo kan to gbe aiye ati orun
Olowo ori awa oo
Ekun to koja gbogbo oke pata
Ode lati wa so ekun derin
Ode lati wa so egan di ogo
O ti de sarin wa oo, Eku ikale
Oti de sarin wa oo Ema ku ikale o
Oti de sarin wa oo, Ema ku ikale oo

Eee emi mimo, Eee emi mimo
Adaba mimo odeee orun, Eku ikale
Ola san lo nile gbogbo eyan to n wo wa ebu ti yin
Erin po nile gbogbo eyan to n wo wa ema ko ti yin
Ekun tan, oshee gbe danu
Ogo bori ogun agbara…

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *