Gospel Songs

Olowogbogboro – Sola Alo (Mp3 and Lyrics)

Olowogbogboro by Sola Alo Mp3 and Lyrics

Download Olowogbogboro Mp3 by Sola Alo

Download Mp3

My Money

Fast rising gospel Star based in the UKSola Alo released a brand new single titled “Olowogbogboro” produced by Shola Williams.

Olowogbogboro, a Yoruba titled track translates as “the Outstretched hands of God” in English language exudes that God is able to deliver and save his children from evil and dangers.

Sola is Writer, lawyer, an actress,a film producer, a music Writer /composer and a talented gospel singer.. She has produced many albums and gospel hits over the years. She has created lots of inspirational songs into the Nigerian music industry. she is Currently the CEO of a record label called PMP “PARADISE MUSIC & FILM PRODUCTION ” a subsidiary of “paradise of truth ministry”.

Olowogbogboro Lyrics by Sola Alo

[Intro]
uuuuummmm
Olowogbogboro  otiwole de
Olowogbogboro otiwole de…..

[Verse 1]
Owole de, Olowogbogboro wole de,
Oma wole de, oba to wo igba aisan wole de,
Isoro re ateriba, olubukun orun seri ibukun lewa Lori ,
Ilu ti ojagun fun lao fifun o,
Ibi ti ogbin si, wa ri ere konibe ,
Anu oluwa, yio sawari ire, gbogbo ire ato wa, Olowogbogboro ti wole de..

  Frank Edwards - Who Run Tings?

[Chorus]
Olowogbogboro ti wole de,
Olowogbogboro ti wole de,
Atun ayere to òré silekun okan re kogba re Olowogbogboro Olowogbogboro Olowogbogboro ti wole de…

[Verse 2]
Bose wole de o, oniro banuje adalayo,
Aro Arin, afoju ariran,
Odi gbohun oluwa , agan aromo gbejo,
Àwon alaisan agba imularada, Olowogbogboro wole de…

[Chorus 2]
Olowogbogboro, Olowogbogboro Olowogbogboro ti wole de…

[MODULATION]
Olowogbogboro ti wole de,
Olowogbogboro ti wole de,
Atun ayere to òré silekun okan re kogba ire Olowogbogboro Olowogbogboro Olowogbogboro ti wole de….

Olowogbogboro Olowogbogboro Olowogbogboro ti wole de…

[CODA]
Silekun okan re kogba ire…

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *