Gospel Songs

Iranlowo – Bukola Bekes (Mp3, Video and Lyrics)

Iranlowo by Bukola Bekes Mp3, Video and Lyrics

Download Iranlowo Mp3 by Bukola Bekes

Download Mp3

My Money

Video: Iranlowo by Bukola Bekes

Iranlowo Lyrics by Bukola Bekes

[Verse 1]
Emi o gbe oju mi sori oke ran ni
Ibo ni Iranlowo mi yo wa ti wa
Iranlowo mi yo to do Oluwa wa
Ti o da orun oun aye

[Chorus]
Iranlowo mi
Lati odo re ni
Oba to da orun aye
Ran mi lowo Oluwa
Ran mi lowo

[Verse 2]
Oun ki yio je ki ese mi koye
Eniti n pamimo
Kiitogbe beeni kii sun rara o
E no dey sleep o

[Chorus]
Iranlowo mi
Lati odo re ni
Oba to da orun aye
Ran mi lowo Oluwa
Ran mi lowo

Iranlowo mi
Lati odo re ni
Oba to da orun aye
Ran mi lowo Oluwa
Ran mi lowo

[Chorus]
Iranlowo mi
Lati odo re ni
Oba to da orun aye
Ran mi lowo Oluwa
Ran mi lowo
Ran mi lowo
Ran mi lowo
Ran mi lowo

  Bukola Bekes - Gbangba Gbangba (Mp3, Video and Lyrics)

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *