Apex Choir – Ona Ara (Mp3 Download, Lyrics)
Gifted Nigeria gospel music choir singers, songwriters and Worship Leaders, Apex Choir has just released an impressive new track titled “Ona Ara”. And you can get it right here for your easy download!
Download Ona Ara Mp3 by Apex Choir.
Video: Ona Ara by Apex Choir.
Ona Ara Lyrics by Apex Choir.
ônô ara ni eyi je ni gbogbo Ono,
Ono awa maridi lofôro wase,
talo leso talo lewi kowi faye,
ire ire tao ro tele lofise konge wa(2ce.
ae ae aeeeee, ae ae o seun seun)2ce (lofi se konge wa) .
intro
repeat the chrs again.
solo
o mu wa la ogbologbo ewu ja,
ao fayo akorin iyin aleluya (aleluyah)
o pabi da sobi dire funwa bi tobediedomu,.o si funwa ni ibukun atoke wa, o si jaje monu funwa
aee (ae ae ae, ae ae oseun seun) )2ce
ire asepe lose fun wa eniyan
iba se eniyan lose ni, won o ba fowo rewa loju, ibukun orun to fi fun wa po ojowa loju (olutoju gbogbo eran ara) ibare o e)2ce lead twice.
call olutoju gbogbo eran ara
resp ibare o e
call Jesu olutoju eniyan ibare o
resp ibare o e
resp.
call asorire a e.o
resp asorire a e
call ire lopolopo, ire niwa, lotun losi, moni asorire a eee
resp asorire a e
nitoripe
ago wa o okun akunwosile
okan wa yo Tori olusewaye
kikida ope ogo loye e peregede
a o sope o peregede
orin ope.lenu wa o
eee a o sope o peregede.
talking drum and omele time
peregede, ao sope o peregede.
hallelujah rejoice with me, He has done great things for me,
hallelujah rejoice with me is my season of blessings,
hallelujah rejoice with me for he has changed my story, hallelujah rejoice with me glory to the Lord(Hallelujah ) repeat again
intro
Baba lokelo lo nda bira
ibukun lopolopo re o
Jesu dabukun sile mo he mo he