Gospel Songs

BABA Ese – Kennywhite4rew Ft BBO (Mp3 Download, Lyrics)

Nigerian gospel minister, Ogunsuyi Kehinde David widely recognized as Kennywhite4rew, a distinguished gospel musician hailing from Ondo State. With roots firmly grounded in the teachings of Winners Chapel, Minister Kehinde David embarked on his musical journey in 2016.

His unwavering commitment to spreading the message of faith and hope through soul-stirring melodies has garnered admiration.

Studied Computer Science from the National Open University of Nigeria, Minister Kehinde David seamlessly blends his technical expertise with a divine musical gift, creating a harmonious symphony that uplifts spirits and resonates with audiences far and wide.

Download BABA Ese Mp3 by Kennywhite4rew Ft BBO

Download Mp3

My Money

BABA Ese Lyrics by Kennywhite4rew Ft BBO

Ai!
Baba Ese, ése ó eséun ó
O kini mafi San óre ré
Emasé o,Eséun o
Óba mi gbani gbani
Gbani gbani ése ,ese o eséun
Kosoba birééé ésé ó,emasé ooo,éséun o
O nibi téti beré,olorun ése
Nibi ti awa baba mi esé
Nibi ti é muwa loooo,ése o
Émase ooo,éseun ooo

  YADAH - NEVER SEEN (Mp3 Download, Lyrics)

Now we say
Chorus
Baba Emasé,emasé
Eséun oo
Baba émase,IBU Chineke

Aisededé mí ó ma dasere duró o lori mi
Okó mi ése eee
Awon tio féran mi ómá jekan yayó ibanuje Lori mió,ógo foruko yin
Asé Egan lé pada dogó
Baba mi íwo ni
É ma n sagan dolomó
É ma n maró larada
Iru isé iyanu éleyi nikan kó lo wa lówo re oko mi
Iru eleyi ati beè beè lo ni
Á bati datipá bió sólayin
Eyin leforin siwa lenu
Téni ama ko ló o
Alatileyin,Iwo ni
Iwó Lodi wa lowó mu
Loni kájo ririn ajo ogó
Eyin lé má nran édá lowo,alagbara ókunrin ógun
Emà ngbé éda dide,olorun mi
Ogó ton buyó Larà wa tó fin pewa lologó iwó ni
aánu tari,ola tari Iwó ni
Olorun aperiye,Iwo ni iranlowó mi
Ogó forukó yin ninu awon órun
mógaji awón alagbara
Arayé rorun lekan soso,baba mi óko mi
IBU chineke
Séloye emajó
Séloye emayó
Séloye emajó o
Séloye emayó {2×}
eeeeeee

  Gabriel Eziashi - Come Alive ft. Henrisoul (Mp3 Download, Lyrics)

And so we say
Baba Emasé,emasé
Eseun oo
Baba emasé,IBU Chineke

Filling in-(lead)
Lead: baba agba,olorun ese o
Gbani gbani ti aye nsaya,baba mi ese
Oba ti ki Ku,oba ti ki sá
Oba mi koyipo pada

Baba emasé,emasé
Eseun oo
Baba emasé IBU chineke

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *