Gospel Songs

Tope Alabi ft TY Bello – Eru re to ba

A powerful Joint praise titled Logan “Eru re to ba” by Tope Alabi Ft. TY Bello

Nigerian gospel ministers, Tope Alabi and TY Bello joins voices in to birth this amazing song titled “Eru re to ba”, the eight song of her Album “The Spirit of Light” which contains 17 powerful Tracks.

Watch and download the spontaneous worship from TY Bello ft Tope Alabi “Eru re to ba”.

Tope Alabi ft TY Bello – Eru re to ba Mp3 Download

Listen, Download & Enjoy Below

DOWNLOAD MP3

Tope Alabi ft TY Bello – Eru re to ba Lyrics

Erure to ba oo, Erure to ba oo
Oba to s′oro ti ina yo, Erure to ba oo
Erure to ba oo, Erure to ba oo
Olorun to s’oro ti ina yo, Erure to ba oo

Erure tooo ba, Erure too ba oo
Olorun to s′oro ti ina yo, Erure to ba oo
Olorun to s’oro ti ina yo, Erure to ba oo

Iwo to s’oro ti okun pupa gbe o, Erure to ba oo
Iwo to s′oro tokun pupa La oo, Erure to ba oo
Iwo to s′oro ti ina yo, Erure to ba oo
Iwo to s’oro ti ina yo oo, Erure to ba oo
Iwo to fi idin je odindi oba, Erure to ba oo
Erure to ba olorun oo, Erure to ba oo Ah ah

Iwo to so Estheri d′ayaba lojiji, Erure to ba oo
O mu eru kuro laarin eru O wa so eru d’oba ti gbogbo aye n wari fun, Erure to ba ooo
Olorun to s′oro ti ina yo o, Erure to ba oo
Olorun to s’oro ti ina yo o, Erure to ba oo
Eleda to s′oro ti ina jade, Erure to ba oo
O mu omi jade ninu apata wa, Ta lo da bi re o, Erure to ba oo

O se oun t’enikan o le se aye raye, Erure to ba oo
Olorun to s’oro ti ina yo o, Erure to ba oo
Olorun to tun aye awa naa se, Erure to ba oo
Eni ta ti ro pe ko le pa go wa deni to kole ala ruru aah ha, Erure to ba oo

Aya re too ja yan, Aya re too ja yan olori aye, Erure to ba oo
Ooh Aya re ja mi yee ye, Erure to ba oo
Ogo re yio po oooo, Erure to ba oo
Erure to ba oooo, Erure to ba oo
Eru re to ba oooooo, Erure to ba o
Erure to ba oo, Erure to ba oo, Erure to ba oooo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *